<?xml version="1.0"?>
<gconf>
	<dir name="schemas">
		<dir name="apps">
			<dir name="window_list_applet">
				<dir name="prefs">
					<entry name="maximum_size">
						<local_schema short_desc="Ìwọ̀n àtòjọ fèrèsé tó ga jù">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="minimum_size">
						<local_schema short_desc="Ìwọ̀n àtòjọ fèrèsé tó kéré jù">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="move_unminimized_windows">
						<local_schema short_desc="Gbé àwọn fèrèsé lọ sí ààyè-iṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ tí a kò bá fẹ̀ẹ́lójú mọ́ ">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, tí o bá ti ń fe ojú fèrèsé gbe lọ sí ààyè-iṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́.Láì jẹ́ bẹ́ẹ̀,sún sí ààyè-iṣẹ́ fèrèsé náà.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="group_windows">
						<local_schema short_desc="Ìgbà tó yẹ ká pín àwọn fèrèsé">
							<longdesc>Ń sọ ìgbà tí a óò pín àwọn fèrèsé láti inú ìṣàmúlò-ètò kan náà lórí àtòjọ fèrèsé.Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni &quot;rárá&quot;, &quot;aládàáṣe&quot; àti &quot;ìgbà gbogbo&quot;.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="display_all_workspaces">
						<local_schema short_desc="Fi àwọn fèrèsé láti gbogbo àwọn ààyè-iṣẹ́ hàn">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, àtòjọ fèrèsé á fi àwọn fèrèsé láti inú gbogbo àwọn ààyè-iṣẹ́ hàn. Láì jẹ́ bẹ́ẹ̀,yóò kàn ṣàfihàn àwọn fèrèsé láti inú ààyè-iṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
				</dir>
			</dir>
			<dir name="workspace_switcher_applet">
				<dir name="prefs">
					<entry name="num_rows">
						<local_schema short_desc="Àwọn róòlù nínú ìjánu-ìsún ààyè-iṣẹ́">
							<longdesc>Bọ́́tìnì yìí ń sọ ní pàtó iye àwọn róòlù (fún ìlàálẹ̀ ìbú) tàbí àwọṅ kọ́lọ̀mù (fún ìlàálẹ̀òòró) tí ìjánu-ìsún ààyè-iṣẹ́ ń fihàn àwọn ààyè-iṣẹ́ náà. Bọ́tìnì yìí kàn sì wúlòtí bọ́tìnì àwọn ààyè-iṣẹ́_gbogbo_ìṣàfihàn bá jẹ́ òótọ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="display_all_workspaces">
						<local_schema short_desc="Ṣàfihàn gbogbo àwọn ààyè-iṣẹ́">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, ìjánu-ìsún ààyè-iṣẹ́ náà á fi gbogbo àwọn ààyè-iṣẹ́ hàn. Láì jẹ́ bẹ́ẹ̀ yóò kàn fi ààyè-iṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ náà hàn.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="display_workspace_names">
						<local_schema short_desc="Ṣàfihàn àwọn orúkọ ààyè-iṣẹ́">
						</local_schema>
					</entry>
				</dir>
			</dir>
			<dir name="fish_applet">
				<dir name="prefs">
					<entry name="rotate">
						<local_schema short_desc="Yípo lórí àwọn pánẹ́ẹ̀lì òòró">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò ṣàfihàn ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà ẹja tí ó yípo lórí àwọn pánẹ́ẹ̀lì òòró.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="speed">
						<local_schema short_desc="Ìdẹsẹ̀dúró fún férémù kọ̀ọ̀kan">
							<longdesc>Bọ́tìnì yìí ń sọ ní pàtó iye àwọn ìṣísẹ̀ tí férémù kọ̀ọ̀kan á ṣàfihàn.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="frames">
						<local_schema short_desc="Àwọn férémù inú ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà ẹja">
							<longdesc>Bọ́tìnì yìí ń sọ ní pàtó iye férémù tí a óò ṣàfihàn wọn nínú ìṣàfarawé kọ̀ǹpútàẹja.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="command">
						<local_schema short_desc="Àṣẹ láti mu ṣiṣẹ́ lórí ìtẹ̀">
							<longdesc>Bọ́tìnì yìí ń sọ ní pàtó àṣẹ tí a óò gbìyànjú láti mú ṣiṣẹ́ nígbà tí a bá tẹ̀ lórí ẹja.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="image">
						<local_schema short_desc="Pixmap ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà ẹja">
							<longdesc>Bọ́tìnì yìí sọ ní pàtó orúkọ-fáìlì pixmap tí a óò lò fún ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà tí aṣàfihàn nínú ápúlẹ́ẹ̀tì ẹja tó jọ atọ́nà pixmap.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="name">
						<local_schema short_desc="Orúkọ ẹja náà">
							<longdesc>Òmùgọ̀ ẹja ní kò ní lórúkọ. Sọ eja dí alàyè nípa fífun lórúkọ.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
				</dir>
			</dir>
			<dir name="clock_applet">
				<dir name="prefs">
					<entry name="internet_time">
						<local_schema short_desc="Lo àkókò Ítánẹ́ẹ̀tì">
							<longdesc>Ìlò bọ́tìnì yìí nínú GNOME 2.6 ti kúrò láṣà.fún &apos;ìgúnrégé&apos; bọ́tìnì. A tọ́jú ìtọsẹ̀ náà fún ìbámu pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà tó ti pẹ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="unix_time">
						<local_schema short_desc="Lo àkókò UNIX">
							<longdesc>Ìlò bọ́tìnì yìí nínú GNOME 2.6 ti kúrò láṣà.fún &apos;ìgúnrégé&apos; bọ́tìnì. A tọ́jú ìtọsẹ̀ náà fún ìbámu pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà tó ti pẹ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="hour_format">
						<local_schema short_desc="Ìgúnrégé wákàtí">
							<longdesc>Ìlò bọ́tìnì yìí nínú GNOME 2.6 ti kúrò láṣà.fún &apos;ìgúnrégé&apos; bọ́tìnì. A tọ́jú ìtọsẹ̀ náà fún ìbámu pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà tó ti pẹ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="show_week_numbers">
						<local_schema short_desc="Fi àwọn nọ́ńbà ọ̀sẹ̀ inú kàlẹ́ńdà hàn">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, fi àwọn nọ́ńbà ọ̀sẹ̀ inú kàlẹ́ńdà hàn.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="config_tool">
						<local_schema short_desc="Irinṣẹ́ àtòpọ̀ àkókò">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="gmt_time">
						<local_schema short_desc="Lo UTC">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="show_tooltip">
						<local_schema short_desc="Fi déèti hàn nínú ìtalólobó-irinṣẹ́">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, fi déètì hàn nínú ìtalólobó-irinṣẹ́ nígbà tí atọ́ka bá wà lórí aago.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="show_date">
						<local_schema short_desc="Fi déètì hàn nínú aago">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, ṣàfihàn déètì nínú aago gẹ́gẹ́ bí àfíkun àkókò</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="show_seconds">
						<local_schema short_desc="Fi àkókò pẹ̀lú àwọn ìṣísẹ̀ hàn">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́,ṣàfihàn àwọn ìṣísẹ̀ nínú àkókò.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="custom_format">
						<local_schema short_desc="Ìgúnrégé àkànṣẹ́ fún aago">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="format">
						<local_schema short_desc="Ìgúnrégé wákàtí">
						</local_schema>
					</entry>
				</dir>
			</dir>
			<dir name="panel">
				<dir name="objects">
					<entry name="action_type">
						<local_schema short_desc="Irúfẹ́ bọ́tìnì iṣẹ́">
							<longdesc>Irúfẹ́ iṣẹ́ tí bọ́tìnì yìí dúró fún. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni&quot;lọ́ọ̀kì&quot;,&quot;parí iṣẹ́&quot;,&quot;rọ́ọ̀nù&quot;,&quot;wádìí&quot;àti &quot;ìmáwòrán&quot;. Bọ́tìnì yìí kàn wúlòtí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ &quot;ápúlẹ́ẹ̀tì-iṣẹ́&quot;.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="launcher_location">
						<local_schema short_desc="Ààyè Aṣàfilọ́lẹ̀">
							<longdesc>Ààyè fáìlì ojú-iṣẹ́ tó ń ṣàpèjúwe aṣàfilọ́lẹ̀. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́  &quot;nǹkan-aṣàfilọ́lẹ̀&quot;.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="menu_path">
						<local_schema short_desc="Ipa àkóónú àtòjọ-ẹ̀yàn">
							<longdesc>Ipa tí a ti kọ́ àwọn àkóónú àtòjọ-ẹ̀yàn. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnìipa_àtòjọ-ẹ̀yàn_ìlò sì jẹ́ òótọ́ tí bọ́tìnì_nǹkan jẹ́&quot;nǹkan-àtòjọ-ẹ̀yàn&quot;</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="use_menu_path">
						<local_schema short_desc="Lo ipa àkànṣe fún àwọn àkóónú àtòjọ-ẹ̀yàn">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, a lo bọ́tìnì ipa _àtòjọ-ẹ̀yàn gẹ́gẹ́ bíi ipa ti a ti lè̀ kọ́ àwọn àkóónú àtòjọ-ẹ̀yàn.Tó bá jẹ́ irọ́, a máa pa bọ́tìnì ipa_àtòjọ-ẹ̀yàn tì. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́  &quot;nǹkan_àtòjọ-ẹ̀yàn&quot;.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="custom_icon">
						<local_schema short_desc="Áíkànnù tí a lò fún bọ́tìnì nǹkan">
							<longdesc>Ààyè fáìlì àwòrán tí a lò gẹ́gẹ́ bíi áíkànnù fún bọ́tìnì nǹkan náà. bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ &quot;nǹkan-dúrọ́wà&quot; tàbí &quot;nǹkan àtòjọ-ẹ̀yàn&quot; tí bọ́tìnì áíkànnù_àkànṣe_ìlò jẹ́ òótọ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="use_custom_icon">
						<local_schema short_desc="Lo áíkànnù àkànṣe fún bọ́tìnì nǹkan">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, bọ́tìnì áíkànnù_àkànṣe la lò gẹ́gẹ́ bíi áíkànnù àkànṣe fún bọ́tìnì náà. Tó bajẹ́ irọ́ a óò pa bọ́tìnì áíkànnù_àkànṣe tì. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tó bá jẹ́ bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan jẹ́ &quot;nǹkan-àtòjọ-ẹ̀yàn&quot; tàbí &quot;nǹkan-dúrọ́wà&quot;.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="tooltip">
						<local_schema short_desc="Ìtalólobó tí a ṣàfihàn fún dúrọ́wà tàbí àtòjọ-ẹ̀yàn">
							<longdesc>Àyọkà tí a fẹ́ ṣàfihàn rẹ̀ nínú ìtalólobó-irinṣẹ́ fún dúrọ́wà yìí tàbí àtòjọ-ẹ̀yàn yìí. Bọ́tìnìyìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bájẹ́&quot;nǹkan-dúrọwà&quot; tàbí &quot;nǹkan-àtòjọ-ẹ̀yàn&quot;.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="attached_toplevel_id">
						<local_schema short_desc="Pánẹ́ẹ̀lì tí a so mọ́ dúrọ́wà">
							<longdesc>Ohun ìdánimọ̀ pánẹ́ẹ̀lì tí a somọ́ dúrọ́wà yìí. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ &quot;nǹkan-dúrọ́wà&quot;.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="bonobo_iid">
						<local_schema short_desc="Ápúlẹ́ẹ̀tì Bonobo IID">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="locked">
						<local_schema short_desc="Ti nǹkan sínú pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, òǹlò náà lè má gbé ápúlẹ́ẹ̀tì láì jẹ́ pé ó kọ́kọ́ ṣí nǹkan tó ń lo &quot;Má tìí&quot; wùnrẹ̀n-àtòjọ-ẹ̀yàn.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="panel_right_stick">
						<local_schema short_desc="Sọ ìtumọ̀ ipo ajemọ́ igun ìsàlẹ̀/ọ̀tún">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò sọ ìtumọ̀ nǹkan náà ní àjẹmọ́ apá ọ̀tún igun pánẹ́ẹ̀lì (tàbí ìsàlẹ̀ tó bá jẹ́ òòró) náà.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="position">
						<local_schema short_desc="Ipò nǹkan lórí pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Ipò nǹkan pánẹ́ẹ̀lì yìí. Oye nọ́ńbà àwọn písẹ́́ẹ̀lì tó wà láti igun pánẹ́ẹ̀lì apá òsì (tàbí òkè òòró) ni yóò sọ ipò náà ní pàtó.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="toplevel_id">
						<local_schema short_desc="Pánẹ́ẹ̀lì ìpele-òkè tó ní nǹkan nínú">
							<longdesc>Ohun ìdánimọ̀ pánẹ́ẹ̀lì ìpele-òkè tó ní nǹkan yìí nínú.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="object_type">
						<local_schema short_desc="Irúfẹ́ nǹkan pánẹ́ẹ̀lì">
						</local_schema>
					</entry>
				</dir>
				<dir name="toplevels">
					<entry name="animation_speed">
						<local_schema short_desc="Ìyárasí àfarawé Kọ̀ǹpútà">
							<longdesc>Ìyárasí tó yẹ kí àwọn ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà ó ti yọ. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni &quot;falẹ̀&quot;, &quot;àárín&quot; àti &quot;ìyára&quot;. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì àwọn mú ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà_ṣiṣẹ́ bá jẹ́ òótọ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="auto_hide_size">
						<local_schema short_desc="Àwọn písẹ́ẹ̀lì ta lè rí nígbà ìpamọ́">
							<longdesc>Ń sọ ní pàtó iye àwọn písẹ́ẹ̀lì tó fojúhàn nígbà tí a fi páńẹ̀ẹlì náà pamọ́ sí igun kan. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì ìpamọ́_aládàáṣe bá jẹ́ òótọ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="unhide_delay">
						<local_schema short_desc="Ìdádúró àìfipamọ́-aládàáṣe pánẹ́èlì">
							<longdesc>Ń sọ ní pàtó oye ìdádúró ọ̀kẹ́-ìṣísẹ̀ lẹ́yìn tí atọ́ka náà ti wọ agbègbè náà kí pánẹ́ẹ̀lì tó dá farahàn. Ìgbà tí bọ́tìnì ìpamọ́_aládàáṣe bá jẹ́ òótọ́ nìkan ni bọ́tìnì yìí wúlò.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="hide_delay">
						<local_schema short_desc="Ìdádúró ìpamọ́-aládàaṣe pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Ń sọ ní pàtó oye ìdádúró ọ̀kẹ́-ìṣísẹ̀ lẹ́yìn tí atọ́ka náà ti jáde lágbègbè náà kí pánẹ́ẹ̀lì tó di pípamọ́. Ìgbà tí bọ́tìnì ìpamọ́_aládàáṣe bá jẹ́ òótọ́ nìkan ni bọ́tìnì yìí wúlò.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="enable_arrows">
						<local_schema short_desc="Fún àwon atọ́ka-árò lágbára lórí àwọn bọ́tìnì ìpamọ́">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ ò̀ótọ́,a óò gbé àwọn atọ́ka-árò sórí àwọn bọ́tìnì ìpamọ́. Bọ́tìnì yìíkàn wúlò tí àwọn bọ́tìnì_tí a fún lágbára bá jẹ́ òótọ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="enable_buttons">
						<local_schema short_desc="Mú àwọn bọ́tìnì ìpamọ́ ṣiṣẹ́">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ ò̀ótọ́,a óò gbé àwọn bọ́tìnì sí ẹ̀̀̀gbẹ́ pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan tí a lè lò láti gbé pánẹ́ẹ̀lìnáà lọ sí igun ojú kọ̀ǹpútà náà. Yóò sì fi bọ́tìnì kan tó ń ṣàfihàn sílẹ̀</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="enable_animations">
						<local_schema short_desc="Fún àwọn ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà lágbára">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, ìfipamọ́ àti àìfipamọ́ pánẹ́ẹ̀lì yìí á jẹ́ ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà. ní èyí tí kò bá fi ṣẹlẹ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="auto_hide">
						<local_schema short_desc="Ó fi pánẹ́ẹ̀lì pamọ́ sí igun">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò fi pánẹ́ẹ̀lì náà pamọ́ fún ra rẹ̀ sínú igun ojú kọ̀ǹpútà náà nígbà tí atọ́ka náà bá fi agbègbè pánẹ́ẹ̀lì náà sílẹ̀. Gbígbé atọ́ka náà lọ sí igun yẹn lẹ́ẹ̀kan si á fa kí pánẹ́ẹ̀lì náà tún farahàn.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="y_centered">
						<local_schema short_desc="Pánẹ́ẹ̀lì àárín orí ásìsì y">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="x_centered">
						<local_schema short_desc="Pánẹ́ẹ̀lì àárín orí ásìsì x">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="y">
						<local_schema short_desc="Kọ́dínéètì Y pánẹ́èlì">
							<longdesc>Ààyè pánẹ́ẹ̀lì lórí ásìsì y. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò nínú móòdù tí a kò fẹ̀. Nínú móòdù tí a fẹ̀, ṣe ni a pa bọ́tìnì yìí tì ni, a sì gbesí igun ojú kọ̀ǹpútà tí bọ́tìnì ìṣàlàyé sọ ní pàtó.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="x">
						<local_schema short_desc="Kọ́dínéètì X pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Ààyè pánẹ́ẹ̀lì lórí ásìsì x. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò nínú móòdù tí a kò fẹ̀. Nínú móòdù tí a fẹ̀, ṣe ni a pa bọ́tìnì yìí tì ni, a sì gbesí igun ojú kọ̀ǹpútà tí bọ́tìnì ìṣàlàyé sọ ní pàtó</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="size">
						<local_schema short_desc="Ìwọ̀n pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Ìgasí (ìfẹ̀sí fún pánẹ́ẹ̀lì òòró) pánẹ́ẹ̀lì náà. Pánẹ́ẹ̀lì náà ló máa sọ ní àkókò láti rọ́ọ̀nù ìwọ̀n tó kéré jù, tó sì dálé ìwọ̀n ìrísí-lẹ́tà àti àwọn atọ́ka mìíràn. A ti fi ìwọ̀n tó ga jù sí ìdá-mẹ́rin ìgasí ojú kọ̀ǹpútà (tàbí ìfẹ̀sí).</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="orientation">
						<local_schema short_desc="Ìṣàlàyé pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Ìṣàlàyé pánẹ́ẹ̀lì yìí. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni &quot;òkè&quot;, &quot;ìsàlẹ̀&quot;, &quot;òsì&quot;, &quot;ọ̀tún&quot;. Ní móòdù tí a fẹ̀, bọ́tìnì náà ń sọ ní pàtó igun ojú kọ̀ǹpútà tí pánẹ́ẹ̀lì náà wà lórí ẹ. Nínú móòdù tí a kò fẹ̀ ìyàtọ̀ tó wà láàrin &quot;òkè&quot; àti &quot;ìsàlẹ̀&quot; pàtàkì díẹ̀ - méjéèjì fihàn pé èyí ni pánẹ́ẹ̀lì oníbùú - ṣùgbọ́n ó ṣì ń ṣòfófói bí ó ṣe yẹ kí àwọn nǹkan pánẹ́ẹ̀lì ṣe rí Bí àpẹẹrẹ, lórí pánẹ́ẹ̀lì &quot;òkè&quot; bọ́tìnì àòjọ-ẹ̀yan á ta àtòjọ-ẹ̀yàn rẹ̀ sókè nísàlẹ̀ pánẹ́ẹ̀lì náà. Bẹ́ẹ̀, lórí pánẹ́ẹ̀lì &quot;ìsàlẹ̀&quot; a óò ta àtòjọ-ẹ̀yàn náà sókè pánẹ́ẹ̀lì náà..</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="expand">
						<local_schema short_desc="Fẹ̀ẹ́ láti lè gba gbogbo ìfẹ̀sí ojú kọ̀ǹpútà">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà á gba gbogbo ìfẹ̀sí ojú kọ̀ǹpútà náà (ìgasí tí o bá jẹ́ pánẹ́ẹ̀lì olóòró). Nínú móòdù yìí, pánẹ́ẹ̀lì a kàn lè gbé pánẹ́ẹ̀lì sígun ojú kọ̀ǹpútà ni. Tó bá jẹ́ irọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà á kàn tóbi láti gba gbogbo àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì náà, àwọn aṣàfilọ́lẹ̀ àti àwọn bọ́tìnì lórí pánẹ́ẹ̀lì náà.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="monitor">
						<local_schema short_desc="Àpótí ìṣàfihàn Xinerama níbi tí a ti ṣàfihàn pánẹ́ẹ̀lì náà">
							<longdesc>Nínú àgbékalẹ̀-ètò Xinerama, o lè ní àwọn pánẹ́ẹ̀lì lórí àpótí ìṣàfihàn kọ̀ọ̀kan. Bọ́tìnì yìí ń tọ́ka sí àpótí ìṣàfihàn lọ́wọ́lọ́wọ́ tí a ti ṣàfihàn pánẹ́ẹ̀lì náà lé lórí.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="screen">
						<local_schema short_desc="Ojú kọ̀ǹpútà X níbi tí a ti ṣàfihàn pánẹ́ẹ̀lì náà">
							<longdesc>Pẹ̀lú àgbékalẹ̀-ètò ojú kọ̀ǹpútà ọlọ́pọ̀, o lè ní àwọn pánẹ́ẹ̀lì lórí ojú kọ̀ǹpútà kọ̀ọ̀kan. Bọ́tìnì yìí ń tọ́ka sí ojú kọ̀ǹpútà lọ́wọ́lọ́wọ́ tí a ti ṣàfihàn pánẹ́èlì náà.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="name">
						<local_schema short_desc="Orúkọ láti dá pánẹ́ẹ̀lì mọ̀">
							<longdesc>Orúkọ èèyàn tí a lè kà ni èyí, tí o sì lè lò láti tọ́ka sí pánẹ́ẹ̀lì. Ìdí pàtàkì rẹ̀ ni láti ṣe iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi àkọ́lé fèrèsé pánẹ́ẹ̀lì tí ó wúlò nígbà tí à ń tọpa láàrin àwọn pánẹ́ẹ̀lì.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<dir name="background">
						<entry name="rotate">
							<local_schema short_desc="Yí àwòrán po lórí àwọn pánẹ́ẹ̀lì òòró">
								<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò yí àwòrán ẹ̀yìn po tí pánẹ́ẹ̀lì náà bá jẹ́ olóòró.</longdesc>
							</local_schema>
						</entry>
						<entry name="stretch">
							<local_schema short_desc="Na àwòrán sí pánẹ́ẹ̀lì">
								<longdesc>Tí ó bá jẹ́ òótọ́, a óò gbé àwòrán léwọ̀n àwọn ojúùwọ̀n pánẹ́ẹ̀lì. Réṣíò aspect àwòrán áwà bó ṣe wà.</longdesc>
							</local_schema>
						</entry>
						<entry name="fit">
							<local_schema short_desc="Fi àwòrán sí pánẹ́ẹ̀lì">
								<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò ṣe ìgbéléwọ̀n àwòrán (             </longdesc>
							</local_schema>
						</entry>
						<entry name="image">
							<local_schema short_desc="Àwòrán ẹ̀yìn">
								<longdesc>Ń sọ fáìlì tí a óò lò ní pàtó fún ẹ̀yìn àwòrán. Tí àwòrán náà bá ní ṣánẹ́ẹ̀lì alpha a óò tòójọ sórí àwòrán ẹ̀yìn ojú-iṣẹ́.</longdesc>
							</local_schema>
						</entry>
						<entry name="opacity">
							<local_schema short_desc="Dídí àwọ̀ ẹ̀yìn">
								<longdesc>Ń sọ ní pàtó dídí ìgúnrégé àwọ̀ ẹ̀yìn . Tí àwọ̀ náà kò bá dí pátá (fálù tó kéré sí 65535) a óò to àwọ̀ náà pọ̀ sórí àwòrán ẹ̀yìn ojú-iṣẹ́.</longdesc>
							</local_schema>
						</entry>
						<entry name="color">
							<local_schema short_desc="Àwọ̀ ẹ̀yìn">
								<longdesc>Ń sọ níp pàtó àwọ̀ ẹ̀yìn fún pánẹ́ẹ̀lì inú ìgúnrégé #RGB.</longdesc>
							</local_schema>
						</entry>
						<entry name="type">
							<local_schema short_desc="Irúfẹ́ ẹ̀yìn">
								<longdesc>Irúfẹ́ ẹ̀yìn wo la ó lò fún pánẹ́ẹ̀lì yìí. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni &quot;gtk&quot; - a óò lo ẹ̀yìn wíjẹ́ẹ̀tì ìpéwọ̀n GTK+, &quot;àwọ̀&quot; a óò lo bọ́tìnì àwọ̀ gẹ́gẹ́ bíi àwọ̀ ẹ̀yìn tàbí &quot;àwòrán&quot; - àwòrán tí bọ́tìnì àwòrán sọ la ó lò gẹ́gẹ́ bíi ẹ̀yìn.</longdesc>
							</local_schema>
						</entry>
					</dir>
				</dir>
				<dir name="general">
					<entry name="profiles_migrated">
						<local_schema short_desc="Àtòpọ̀ àkópọ̀ ìròyìn àtijọ́ ti ṣí kúrò">
							<longdesc>Àsíá boolean ń fihàn bóyá a ti ṣẹ̀dà àtòpọ̀ òǹlò ilẹ̀ inú /appa/panel/profiles/default sínú ààyè tuntun nínúpánẹ́ẹ̀lì /apps/.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="object_id_list">
						<local_schema short_desc="Àtójọ ID nǹkan pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Àtòjọ àwọn ID ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ń tọ́ka sí nǹkan pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan (b.a.aṣàfilọ́lẹ̀, bọ́tìnì iṣẹ́ tàbí àká/bọ́tìnì àtòjọ-ẹ̀yàn). A fi àwọn ààtò fún àwọn nǹkankọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/objects/$(id).</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="applet_id_list">
						<local_schema short_desc="Àtòjọ ID ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Àtòjọ àwọn ID ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ń tọ́ka sí ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì.A fi àwọn ààtò fún àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/applets/$(id).</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="toplevel_id_list">
						<local_schema short_desc="Àtòjọ ID pánẹ́́ẹ̀lì">
							<longdesc>Àtòjọ àwọn ID pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ló n tọ́ka sí pánẹ́ẹ̀lì ìpele-òkè kọ̀ọ̀kan. A fi àwọnà̀àtò̀ fún àwọn pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/toplevels/$(id).</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="enable_autocompletion">
						<local_schema short_desc="Mú ìkádìí-aládàáṣe nínú onísọ̀rọ̀gbèsì &quot;Rọ́ọ̀nù Ìṣàmúlò-ètò&quot; ṣiṣẹ́">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, ìkádìí-aládàáṣe inú onísọ̀rọ̀gbèsì &quot;Rọ́ọnù Ìṣàmúlò-ètò&quot; wà nílẹ̀.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="show_program_list">
						<local_schema short_desc="Fẹ àtòjọ àtòjọ-ètò inú onísọ̀rọ̀gbèsì &quot;Rọ́ọ̀nù Ìṣàmúlò-ètò&quot; ">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, &quot;Àwọn Ìṣàmúlò-ètò Mímọ̀&quot; tí a tòjọ nínú onísọ̀rọ̀gbèsì &quot;Rọ́ọ̀nù Ìṣàmúlò-ètò&quot;á fẹ̀ nígbà tí a bá ṣí onísọ̀rọ̀gbèsì. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì àtòjọ_àtòjọ-ètò_ bá jẹ́ òótọ́.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="enable_program_list">
						<local_schema short_desc="Mú àtòjọ àtòjọ-ètò inú onísọ̀rọ̀gbèsì &quot;Rọ́ọ̀nù Ìsàmúlò-ètò&quot; ṣíṣẹ">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, &quot;Àwọn Ìṣàmúlò-ètò Mímọ̀&quot; tía tòjọ nínú onísọ̀rọ̀gbèsì &quot;Rọ́ọ̀nù Ìsàmúlò-ètò&quot;wà nílẹ̀. Bóyá a fẹ ìṣàtòjọ náà tàbí a kò fẹ̀ẹ́, nígbà tí onísọ̀rọ̀gbèsì náà bá ti farahàn bọ́tìnì àtòjọ_àtòjọ-ètò_ìfihàn ló ń darí rẹ̀.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
				</dir>
				<dir name="global">
					<entry name="disable_force_quit">
						<local_schema short_desc="Gba agbára lọ́wọ́ Ìjáde Ipá">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà kò ní fàyè gba òǹlò láti mú ìṣàmúlò-ètò jáde pẹ̀lú ipánípa yíyọ ààyè sí bọ́tìnì ìjáde ipá kúrò.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="disable_log_out">
						<local_schema short_desc="Gba agbára Píparí Iṣẹ́">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà kò ní fàyè gba òǹlò láti parí iṣẹ́ nípa yíyọ ààyèsí àwọn àmúwọlé àtòjọ-ẹ̀yàn ìparí iṣẹ́ kúrò.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="disable_lock_screen">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="disabled_applets">
						<local_schema short_desc="Àwọn IID ápúlẹ́ẹ̀tì tí a kò jẹ́ kí wọn kì">
							<longdesc>Àtòjọ àwọn IID ápúlẹ́ẹ̀tì tí pánẹ́ẹ̀lì máa patì. Lọ́nà yìí o lè gba agbára àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì kan láti má ma ki àtòjọ-ẹ̀yàn tàbí fihàn nínú àtòjọ-ẹ̀yàn náà. Bí àpẹẹrẹ, láti lè gbaagbára ápúlẹ́ẹ̀tì aláṣẹ́-kékeré ṣàfikún &apos;OAFIID:GNOME_MiniCommanderApplet&apos; sí àtòjọ yìí. A gbọ́dọ̀ tún pánẹ́ẹ̀lì náà bẹ̀rẹ̀ kí èyí tó lè wáyé.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="locked_down">
						<local_schema short_desc="Lọ́ọ̀kì pánẹ́ẹ̀lì ìkádìí">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà kò ní fàyè gba àwọn ìyípadà kankan sí àtòpọ̀ pánẹ́ẹ̀lì náà.Ṣùgbọ́n a sì ní láti ti àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì kọ̀ọ̀kan ná. A gbọ́dọ̀tún pánẹ́ẹ̀lì náà bẹ̀rẹ̀ kí èyí tó lè wáyé.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="highlight_launchers_on_mouseover">
						<local_schema short_desc="Gbé àwon aṣàfilọ́lẹ̀ yọ lórí ohun-èlò aṣèkúté">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, aṣàfilọ́lẹ̀ kan á yọ nígbà tí òǹlò náà bá gbé atọ́ka náà gba orí ẹ̀.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="confirm_panel_remove">
						<local_schema short_desc="Àrídájú ìyọkúrò pánẹ́ẹ̀lì">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́,onísọ̀rọ̀gbèsì kàn ti farahàn tó ń bèrè fún àrídájú tó bá jẹ́ pé òǹlò fẹ́ yọ Pánẹ́ẹ̀lì kúrò.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="drawer_autoclose">
						<local_schema short_desc="Dúrọ́wà Aládàátì">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, dúrọ́wà á tì fún ra rẹ̀ nígbà tí òǹlò bá ti tẹaṣàfilọ̀lẹ̀ nínú ẹ̀.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="window_screenshot_key">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="screenshot_key">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="run_key">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="menu_key">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="enable_key_bindings">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="panel_hide_delay">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="panel_animation_speed">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="panel_show_delay">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="panel_minimized_size">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="enable_animations">
						<local_schema short_desc="Fún àwọn ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà lágbára">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="keep_menus_in_memory">
						<local_schema short_desc="Ó ti kúrò láṣà">
						</local_schema>
					</entry>
					<entry name="tooltips_enabled">
						<local_schema short_desc="Fún àwọn ìtalólobó-irinṣẹ́ lágbára">
							<longdesc>Tó bá jẹ́ òótọ́, a fi àwọn ìtalólobó-irinṣẹ́ hàn fún àwọn nǹkan inú àwọn pánẹ́ẹ̀lì.</longdesc>
						</local_schema>
					</entry>
				</dir>
			</dir>
		</dir>
	</dir>
</gconf>