Tó bá jẹ́ òótọ́, tí o bá ti ń fe ojú fèrèsé gbe lọ sí ààyè-iṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́.Láì jẹ́ bẹ́ẹ̀,sún sí ààyè-iṣẹ́ fèrèsé náà. Ń sọ ìgbà tí a óò pín àwọn fèrèsé láti inú ìṣàmúlò-ètò kan náà lórí àtòjọ fèrèsé.Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni "rárá", "aládàáṣe" àti "ìgbà gbogbo". Tó bá jẹ́ òótọ́, àtòjọ fèrèsé á fi àwọn fèrèsé láti inú gbogbo àwọn ààyè-iṣẹ́ hàn. Láì jẹ́ bẹ́ẹ̀,yóò kàn ṣàfihàn àwọn fèrèsé láti inú ààyè-iṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni. Bọ́́tìnì yìí ń sọ ní pàtó iye àwọn róòlù (fún ìlàálẹ̀ ìbú) tàbí àwọṅ kọ́lọ̀mù (fún ìlàálẹ̀òòró) tí ìjánu-ìsún ààyè-iṣẹ́ ń fihàn àwọn ààyè-iṣẹ́ náà. Bọ́tìnì yìí kàn sì wúlòtí bọ́tìnì àwọn ààyè-iṣẹ́_gbogbo_ìṣàfihàn bá jẹ́ òótọ́. Tó bá jẹ́ òótọ́, ìjánu-ìsún ààyè-iṣẹ́ náà á fi gbogbo àwọn ààyè-iṣẹ́ hàn. Láì jẹ́ bẹ́ẹ̀ yóò kàn fi ààyè-iṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ náà hàn. Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò ṣàfihàn ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà ẹja tí ó yípo lórí àwọn pánẹ́ẹ̀lì òòró. Bọ́tìnì yìí ń sọ ní pàtó iye àwọn ìṣísẹ̀ tí férémù kọ̀ọ̀kan á ṣàfihàn. Bọ́tìnì yìí ń sọ ní pàtó iye férémù tí a óò ṣàfihàn wọn nínú ìṣàfarawé kọ̀ǹpútàẹja. Bọ́tìnì yìí ń sọ ní pàtó àṣẹ tí a óò gbìyànjú láti mú ṣiṣẹ́ nígbà tí a bá tẹ̀ lórí ẹja. Bọ́tìnì yìí sọ ní pàtó orúkọ-fáìlì pixmap tí a óò lò fún ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà tí aṣàfihàn nínú ápúlẹ́ẹ̀tì ẹja tó jọ atọ́nà pixmap. Òmùgọ̀ ẹja ní kò ní lórúkọ. Sọ eja dí alàyè nípa fífun lórúkọ. Ìlò bọ́tìnì yìí nínú GNOME 2.6 ti kúrò láṣà.fún 'ìgúnrégé' bọ́tìnì. A tọ́jú ìtọsẹ̀ náà fún ìbámu pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà tó ti pẹ́. Ìlò bọ́tìnì yìí nínú GNOME 2.6 ti kúrò láṣà.fún 'ìgúnrégé' bọ́tìnì. A tọ́jú ìtọsẹ̀ náà fún ìbámu pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà tó ti pẹ́. Ìlò bọ́tìnì yìí nínú GNOME 2.6 ti kúrò láṣà.fún 'ìgúnrégé' bọ́tìnì. A tọ́jú ìtọsẹ̀ náà fún ìbámu pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà tó ti pẹ́. Tó bá jẹ́ òótọ́, fi àwọn nọ́ńbà ọ̀sẹ̀ inú kàlẹ́ńdà hàn. Tó bá jẹ́ òótọ́, fi déètì hàn nínú ìtalólobó-irinṣẹ́ nígbà tí atọ́ka bá wà lórí aago. Tó bá jẹ́ òótọ́, ṣàfihàn déètì nínú aago gẹ́gẹ́ bí àfíkun àkókò Tó bá jẹ́ òótọ́,ṣàfihàn àwọn ìṣísẹ̀ nínú àkókò. Irúfẹ́ iṣẹ́ tí bọ́tìnì yìí dúró fún. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni"lọ́ọ̀kì","parí iṣẹ́","rọ́ọ̀nù","wádìí"àti "ìmáwòrán". Bọ́tìnì yìí kàn wúlòtí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ "ápúlẹ́ẹ̀tì-iṣẹ́". Ààyè fáìlì ojú-iṣẹ́ tó ń ṣàpèjúwe aṣàfilọ́lẹ̀. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ "nǹkan-aṣàfilọ́lẹ̀". Ipa tí a ti kọ́ àwọn àkóónú àtòjọ-ẹ̀yàn. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnìipa_àtòjọ-ẹ̀yàn_ìlò sì jẹ́ òótọ́ tí bọ́tìnì_nǹkan jẹ́"nǹkan-àtòjọ-ẹ̀yàn" Tó bá jẹ́ òótọ́, a lo bọ́tìnì ipa _àtòjọ-ẹ̀yàn gẹ́gẹ́ bíi ipa ti a ti lè̀ kọ́ àwọn àkóónú àtòjọ-ẹ̀yàn.Tó bá jẹ́ irọ́, a máa pa bọ́tìnì ipa_àtòjọ-ẹ̀yàn tì. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ "nǹkan_àtòjọ-ẹ̀yàn". Ààyè fáìlì àwòrán tí a lò gẹ́gẹ́ bíi áíkànnù fún bọ́tìnì nǹkan náà. bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ "nǹkan-dúrọ́wà" tàbí "nǹkan àtòjọ-ẹ̀yàn" tí bọ́tìnì áíkànnù_àkànṣe_ìlò jẹ́ òótọ́. Tó bá jẹ́ òótọ́, bọ́tìnì áíkànnù_àkànṣe la lò gẹ́gẹ́ bíi áíkànnù àkànṣe fún bọ́tìnì náà. Tó bajẹ́ irọ́ a óò pa bọ́tìnì áíkànnù_àkànṣe tì. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tó bá jẹ́ bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan jẹ́ "nǹkan-àtòjọ-ẹ̀yàn" tàbí "nǹkan-dúrọ́wà". Àyọkà tí a fẹ́ ṣàfihàn rẹ̀ nínú ìtalólobó-irinṣẹ́ fún dúrọ́wà yìí tàbí àtòjọ-ẹ̀yàn yìí. Bọ́tìnìyìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bájẹ́"nǹkan-dúrọwà" tàbí "nǹkan-àtòjọ-ẹ̀yàn". Ohun ìdánimọ̀ pánẹ́ẹ̀lì tí a somọ́ dúrọ́wà yìí. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì irúfẹ́_nǹkan bá jẹ́ "nǹkan-dúrọ́wà". Tó bá jẹ́ òótọ́, òǹlò náà lè má gbé ápúlẹ́ẹ̀tì láì jẹ́ pé ó kọ́kọ́ ṣí nǹkan tó ń lo "Má tìí" wùnrẹ̀n-àtòjọ-ẹ̀yàn. Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò sọ ìtumọ̀ nǹkan náà ní àjẹmọ́ apá ọ̀tún igun pánẹ́ẹ̀lì (tàbí ìsàlẹ̀ tó bá jẹ́ òòró) náà. Ipò nǹkan pánẹ́ẹ̀lì yìí. Oye nọ́ńbà àwọn písẹ́́ẹ̀lì tó wà láti igun pánẹ́ẹ̀lì apá òsì (tàbí òkè òòró) ni yóò sọ ipò náà ní pàtó. Ohun ìdánimọ̀ pánẹ́ẹ̀lì ìpele-òkè tó ní nǹkan yìí nínú. Ìyárasí tó yẹ kí àwọn ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà ó ti yọ. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni "falẹ̀", "àárín" àti "ìyára". Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì àwọn mú ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà_ṣiṣẹ́ bá jẹ́ òótọ́. Ń sọ ní pàtó iye àwọn písẹ́ẹ̀lì tó fojúhàn nígbà tí a fi páńẹ̀ẹlì náà pamọ́ sí igun kan. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì ìpamọ́_aládàáṣe bá jẹ́ òótọ́. Ń sọ ní pàtó oye ìdádúró ọ̀kẹ́-ìṣísẹ̀ lẹ́yìn tí atọ́ka náà ti wọ agbègbè náà kí pánẹ́ẹ̀lì tó dá farahàn. Ìgbà tí bọ́tìnì ìpamọ́_aládàáṣe bá jẹ́ òótọ́ nìkan ni bọ́tìnì yìí wúlò. Ń sọ ní pàtó oye ìdádúró ọ̀kẹ́-ìṣísẹ̀ lẹ́yìn tí atọ́ka náà ti jáde lágbègbè náà kí pánẹ́ẹ̀lì tó di pípamọ́. Ìgbà tí bọ́tìnì ìpamọ́_aládàáṣe bá jẹ́ òótọ́ nìkan ni bọ́tìnì yìí wúlò. Tó bá jẹ́ ò̀ótọ́,a óò gbé àwọn atọ́ka-árò sórí àwọn bọ́tìnì ìpamọ́. Bọ́tìnì yìíkàn wúlò tí àwọn bọ́tìnì_tí a fún lágbára bá jẹ́ òótọ́. Tó bá jẹ́ ò̀ótọ́,a óò gbé àwọn bọ́tìnì sí ẹ̀̀̀gbẹ́ pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan tí a lè lò láti gbé pánẹ́ẹ̀lìnáà lọ sí igun ojú kọ̀ǹpútà náà. Yóò sì fi bọ́tìnì kan tó ń ṣàfihàn sílẹ̀ Tó bá jẹ́ òótọ́, ìfipamọ́ àti àìfipamọ́ pánẹ́ẹ̀lì yìí á jẹ́ ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà. ní èyí tí kò bá fi ṣẹlẹ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀. Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò fi pánẹ́ẹ̀lì náà pamọ́ fún ra rẹ̀ sínú igun ojú kọ̀ǹpútà náà nígbà tí atọ́ka náà bá fi agbègbè pánẹ́ẹ̀lì náà sílẹ̀. Gbígbé atọ́ka náà lọ sí igun yẹn lẹ́ẹ̀kan si á fa kí pánẹ́ẹ̀lì náà tún farahàn. Ààyè pánẹ́ẹ̀lì lórí ásìsì y. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò nínú móòdù tí a kò fẹ̀. Nínú móòdù tí a fẹ̀, ṣe ni a pa bọ́tìnì yìí tì ni, a sì gbesí igun ojú kọ̀ǹpútà tí bọ́tìnì ìṣàlàyé sọ ní pàtó. Ààyè pánẹ́ẹ̀lì lórí ásìsì x. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò nínú móòdù tí a kò fẹ̀. Nínú móòdù tí a fẹ̀, ṣe ni a pa bọ́tìnì yìí tì ni, a sì gbesí igun ojú kọ̀ǹpútà tí bọ́tìnì ìṣàlàyé sọ ní pàtó Ìgasí (ìfẹ̀sí fún pánẹ́ẹ̀lì òòró) pánẹ́ẹ̀lì náà. Pánẹ́ẹ̀lì náà ló máa sọ ní àkókò láti rọ́ọ̀nù ìwọ̀n tó kéré jù, tó sì dálé ìwọ̀n ìrísí-lẹ́tà àti àwọn atọ́ka mìíràn. A ti fi ìwọ̀n tó ga jù sí ìdá-mẹ́rin ìgasí ojú kọ̀ǹpútà (tàbí ìfẹ̀sí). Ìṣàlàyé pánẹ́ẹ̀lì yìí. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni "òkè", "ìsàlẹ̀", "òsì", "ọ̀tún". Ní móòdù tí a fẹ̀, bọ́tìnì náà ń sọ ní pàtó igun ojú kọ̀ǹpútà tí pánẹ́ẹ̀lì náà wà lórí ẹ. Nínú móòdù tí a kò fẹ̀ ìyàtọ̀ tó wà láàrin "òkè" àti "ìsàlẹ̀" pàtàkì díẹ̀ - méjéèjì fihàn pé èyí ni pánẹ́ẹ̀lì oníbùú - ṣùgbọ́n ó ṣì ń ṣòfófói bí ó ṣe yẹ kí àwọn nǹkan pánẹ́ẹ̀lì ṣe rí Bí àpẹẹrẹ, lórí pánẹ́ẹ̀lì "òkè" bọ́tìnì àòjọ-ẹ̀yan á ta àtòjọ-ẹ̀yàn rẹ̀ sókè nísàlẹ̀ pánẹ́ẹ̀lì náà. Bẹ́ẹ̀, lórí pánẹ́ẹ̀lì "ìsàlẹ̀" a óò ta àtòjọ-ẹ̀yàn náà sókè pánẹ́ẹ̀lì náà.. Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà á gba gbogbo ìfẹ̀sí ojú kọ̀ǹpútà náà (ìgasí tí o bá jẹ́ pánẹ́ẹ̀lì olóòró). Nínú móòdù yìí, pánẹ́ẹ̀lì a kàn lè gbé pánẹ́ẹ̀lì sígun ojú kọ̀ǹpútà ni. Tó bá jẹ́ irọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà á kàn tóbi láti gba gbogbo àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì náà, àwọn aṣàfilọ́lẹ̀ àti àwọn bọ́tìnì lórí pánẹ́ẹ̀lì náà. Nínú àgbékalẹ̀-ètò Xinerama, o lè ní àwọn pánẹ́ẹ̀lì lórí àpótí ìṣàfihàn kọ̀ọ̀kan. Bọ́tìnì yìí ń tọ́ka sí àpótí ìṣàfihàn lọ́wọ́lọ́wọ́ tí a ti ṣàfihàn pánẹ́ẹ̀lì náà lé lórí. Pẹ̀lú àgbékalẹ̀-ètò ojú kọ̀ǹpútà ọlọ́pọ̀, o lè ní àwọn pánẹ́ẹ̀lì lórí ojú kọ̀ǹpútà kọ̀ọ̀kan. Bọ́tìnì yìí ń tọ́ka sí ojú kọ̀ǹpútà lọ́wọ́lọ́wọ́ tí a ti ṣàfihàn pánẹ́èlì náà. Orúkọ èèyàn tí a lè kà ni èyí, tí o sì lè lò láti tọ́ka sí pánẹ́ẹ̀lì. Ìdí pàtàkì rẹ̀ ni láti ṣe iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi àkọ́lé fèrèsé pánẹ́ẹ̀lì tí ó wúlò nígbà tí à ń tọpa láàrin àwọn pánẹ́ẹ̀lì. Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò yí àwòrán ẹ̀yìn po tí pánẹ́ẹ̀lì náà bá jẹ́ olóòró. Tí ó bá jẹ́ òótọ́, a óò gbé àwòrán léwọ̀n àwọn ojúùwọ̀n pánẹ́ẹ̀lì. Réṣíò aspect àwòrán áwà bó ṣe wà. Tó bá jẹ́ òótọ́, a óò ṣe ìgbéléwọ̀n àwòrán ( Ń sọ fáìlì tí a óò lò ní pàtó fún ẹ̀yìn àwòrán. Tí àwòrán náà bá ní ṣánẹ́ẹ̀lì alpha a óò tòójọ sórí àwòrán ẹ̀yìn ojú-iṣẹ́. Ń sọ ní pàtó dídí ìgúnrégé àwọ̀ ẹ̀yìn . Tí àwọ̀ náà kò bá dí pátá (fálù tó kéré sí 65535) a óò to àwọ̀ náà pọ̀ sórí àwòrán ẹ̀yìn ojú-iṣẹ́. Ń sọ níp pàtó àwọ̀ ẹ̀yìn fún pánẹ́ẹ̀lì inú ìgúnrégé #RGB. Irúfẹ́ ẹ̀yìn wo la ó lò fún pánẹ́ẹ̀lì yìí. Àwọn fálù tó lè jẹ́ ni "gtk" - a óò lo ẹ̀yìn wíjẹ́ẹ̀tì ìpéwọ̀n GTK+, "àwọ̀" a óò lo bọ́tìnì àwọ̀ gẹ́gẹ́ bíi àwọ̀ ẹ̀yìn tàbí "àwòrán" - àwòrán tí bọ́tìnì àwòrán sọ la ó lò gẹ́gẹ́ bíi ẹ̀yìn. Àsíá boolean ń fihàn bóyá a ti ṣẹ̀dà àtòpọ̀ òǹlò ilẹ̀ inú /appa/panel/profiles/default sínú ààyè tuntun nínúpánẹ́ẹ̀lì /apps/. Àtòjọ àwọn ID ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ń tọ́ka sí nǹkan pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan (b.a.aṣàfilọ́lẹ̀, bọ́tìnì iṣẹ́ tàbí àká/bọ́tìnì àtòjọ-ẹ̀yàn). A fi àwọn ààtò fún àwọn nǹkankọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/objects/$(id). Àtòjọ àwọn ID ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ń tọ́ka sí ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì.A fi àwọn ààtò fún àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/applets/$(id). Àtòjọ àwọn ID pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ló n tọ́ka sí pánẹ́ẹ̀lì ìpele-òkè kọ̀ọ̀kan. A fi àwọnà̀àtò̀ fún àwọn pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/toplevels/$(id). Tó bá jẹ́ òótọ́, ìkádìí-aládàáṣe inú onísọ̀rọ̀gbèsì "Rọ́ọnù Ìṣàmúlò-ètò" wà nílẹ̀. Tó bá jẹ́ òótọ́, "Àwọn Ìṣàmúlò-ètò Mímọ̀" tí a tòjọ nínú onísọ̀rọ̀gbèsì "Rọ́ọ̀nù Ìṣàmúlò-ètò"á fẹ̀ nígbà tí a bá ṣí onísọ̀rọ̀gbèsì. Bọ́tìnì yìí kàn wúlò tí bọ́tìnì àtòjọ_àtòjọ-ètò_ bá jẹ́ òótọ́. Tó bá jẹ́ òótọ́, "Àwọn Ìṣàmúlò-ètò Mímọ̀" tía tòjọ nínú onísọ̀rọ̀gbèsì "Rọ́ọ̀nù Ìsàmúlò-ètò"wà nílẹ̀. Bóyá a fẹ ìṣàtòjọ náà tàbí a kò fẹ̀ẹ́, nígbà tí onísọ̀rọ̀gbèsì náà bá ti farahàn bọ́tìnì àtòjọ_àtòjọ-ètò_ìfihàn ló ń darí rẹ̀. Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà kò ní fàyè gba òǹlò láti mú ìṣàmúlò-ètò jáde pẹ̀lú ipánípa yíyọ ààyè sí bọ́tìnì ìjáde ipá kúrò. Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà kò ní fàyè gba òǹlò láti parí iṣẹ́ nípa yíyọ ààyèsí àwọn àmúwọlé àtòjọ-ẹ̀yàn ìparí iṣẹ́ kúrò. Àtòjọ àwọn IID ápúlẹ́ẹ̀tì tí pánẹ́ẹ̀lì máa patì. Lọ́nà yìí o lè gba agbára àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì kan láti má ma ki àtòjọ-ẹ̀yàn tàbí fihàn nínú àtòjọ-ẹ̀yàn náà. Bí àpẹẹrẹ, láti lè gbaagbára ápúlẹ́ẹ̀tì aláṣẹ́-kékeré ṣàfikún 'OAFIID:GNOME_MiniCommanderApplet' sí àtòjọ yìí. A gbọ́dọ̀ tún pánẹ́ẹ̀lì náà bẹ̀rẹ̀ kí èyí tó lè wáyé. Tó bá jẹ́ òótọ́, pánẹ́ẹ̀lì náà kò ní fàyè gba àwọn ìyípadà kankan sí àtòpọ̀ pánẹ́ẹ̀lì náà.Ṣùgbọ́n a sì ní láti ti àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì kọ̀ọ̀kan ná. A gbọ́dọ̀tún pánẹ́ẹ̀lì náà bẹ̀rẹ̀ kí èyí tó lè wáyé. Tó bá jẹ́ òótọ́, aṣàfilọ́lẹ̀ kan á yọ nígbà tí òǹlò náà bá gbé atọ́ka náà gba orí ẹ̀. Tó bá jẹ́ òótọ́,onísọ̀rọ̀gbèsì kàn ti farahàn tó ń bèrè fún àrídájú tó bá jẹ́ pé òǹlò fẹ́ yọ Pánẹ́ẹ̀lì kúrò. Tó bá jẹ́ òótọ́, dúrọ́wà á tì fún ra rẹ̀ nígbà tí òǹlò bá ti tẹaṣàfilọ̀lẹ̀ nínú ẹ̀. Tó bá jẹ́ òótọ́, a fi àwọn ìtalólobó-irinṣẹ́ hàn fún àwọn nǹkan inú àwọn pánẹ́ẹ̀lì.